Black November | |
---|---|
[[File:|200px|alt=]] Theatrical release poster | |
Adarí | Jeta Amata |
Olùgbékalẹ̀ | Bernard Alexander Jeta Amata Ori Ayonmike Marc Byers Wilson Ebiye Hakeem Kae-Kazim Dede Mabiaku |
Òǹkọ̀wé | Jeta Amata |
Asọ̀tàn | Kara Noble |
Àwọn òṣèré | |
Orin | Joel Goffin |
Ìyàwòrán sinimá | James Michael Costello Tommy Maddox-Upshaw |
Olóòtú | Debbie Berman Lindsay Kent Adam Varney |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Wells & Jeta Entertainment |
Olùpín | eOne Entertainment (United States) |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 95 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria United States |
Èdè | English |
Ìnáwó | ₦2 billion (shared with Black Gold)[1] (US$12.5 million) |
Black November: Struggle for the Niger Delta jẹ́ fíìmù Nàìjíríà tó tan mọ́ ti ilẹ̀ Hakeem Kae-Kazim, Mickey Rourke, Kim Basinger, Fred Amata, Sarah Wayne Callies, Nse Ikpe-Etim, OC Ukeje, Vivica Fox, Anne Heche, Persia White, Akon, Wyclef Jean àti Mbong Amata ló kópa nínú fíìmù náà. [2][3] Jeta Amata ni olùdarí fíìmù yìí, ìtàn náà sì dá lórí ìtàn agbègbè Niger Delta àti akitiyan wọ́n láti ṣe lòdì sí ìjọba tó ń ba ìlú náà jẹ́, àti láti ṣe ìràpadà ìlú wọn tó ti ń lọ sí oko ìparun látàrí epo rọ̀bì tí wọ́n ń jí bù. [4]
Àkọlé yìí, ìyẹn Black November wáyé látàrí ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ ní oṣù náà, nígbà tí wọ́n pa ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn, ìyẹn Ken Saro-Wiwa ní ọdún 1995 [5] Fíìmù yìí fẹ́ fara jọ fíìmù ọdún 2011 kan, tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Black Gold.Wọ́n tún àwọn ìran kan yà, wọ́n sì ṣàfikún sí fíìmù náà. .[6] Bernard Alexander Ori Ayonmike, Marc Byers, Wilson Ebiye, Hakeem Kae-Kazim àti Dede Mabiaku ló ṣàgbéjáde fíìmù Black November. Owó tí wọ́n fi àgbéjáde fíìmù yìí wọ US$22 million,[7] èyí tí ó ti ọwọ́ elépo rọ̀bì kan wá. [7]
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)